I. Pet 3:12
I. Pet 3:12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori oju Oluwa mbẹ lara awọn olododo, etí rẹ̀ si ṣí si ẹbẹ wọn: ṣugbọn oju Oluwa nwo awọn ti nṣe buburu.
Pín
Kà I. Pet 3I. Pet 3:12 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí Oluwa ń ṣọ́ àwọn olódodo, ó sì dẹ etí sí ẹ̀bẹ̀ wọn. Ṣugbọn ojú Oluwa kan sí àwọn tí ó ń ṣe burúkú.”
Pín
Kà I. Pet 3