I. Kor 4:12
I. Kor 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Tí a ń fi ọwọ́ ara wa ṣiṣẹ́, wọn ń gàn wa, àwa ń súre, wọn ń ṣe inúnibíni sí wa, àwa ń forítì i.
Pín
Kà I. Kor 4I. Kor 4:12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ti a nṣe lãlã, a nfi ọwọ́ ara wa ṣiṣẹ: nwọn ngàn wa, awa nsure; nwọn nṣe inunibini si wa, awa nforitì i
Pín
Kà I. Kor 4