I. Kor 15:20-21
I. Kor 15:20-21 Bibeli Mimọ (YBCV)
Njẹ nisisiyi Kristi ti jinde kuro ninu okú, o si di akọbi ninu awọn ti o sùn. Nitori igbati o ti ṣepe nipa enia ni ikú ti wá, nipa enia li ajinde ninu okú si ti wá pẹlu.
Pín
Kà I. Kor 15