Njẹ onirũru ẹ̀bun li o wà, ṣugbọn Ẹmí kanna ni.
Oríṣìíríṣìí ni ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ ṣugbọn láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí kan náà ni wọ́n ti ń wá.
Ǹjẹ́ onírúurú ẹ̀bùn ni ó wà, ṣùgbọ́n Ẹ̀mí kan náà ni o ń pín wọn.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò