I. Kor 12:25
I. Kor 12:25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ki ìyapa ki o máṣe si ninu ara; ṣugbọn ki awọn ẹ̀ya ara ki o le mã ṣe aniyan kanna fun ara wọn.
Pín
Kà I. Kor 12I. Kor 12:25 Yoruba Bible (YCE)
kí ó má baà sí ìyapa ninu ara, ṣugbọn kí gbogbo àwọn ẹ̀yà ara lè máa ṣe aájò kan náà fún ara wọn.
Pín
Kà I. Kor 12