I. Kor 10:31
I. Kor 10:31 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitorina bi ẹnyin ba njẹ, tabi bi ẹnyin ba nmu, tabi ohunkohun ti ẹnyin ba nṣe, ẹ mã ṣe gbogbo wọn fun ogo Ọlọrun.
Pín
Kà I. Kor 10I. Kor 10:31 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí náà, ìbáà jẹ́ pé ẹ̀ ń jẹ ni, tabi pé ẹ̀ ń mu ni, ohunkohun tí ẹ bá ń ṣe, ẹ máa ṣe é fún ògo Ọlọrun.
Pín
Kà I. Kor 10