I. Kro 22:19
I. Kro 22:19 Bibeli Mimọ (YBCV)
Njẹ nisisiyi ẹ fi aiya nyin ati ọkàn nyin si atiwá Oluwa Ọlọrun nyin; nitorina dide ki ẹ si kọ́ ibi mimọ́ Oluwa Ọlọrun, lati mu apoti ẹri ti majẹmu Oluwa wọ̀ inu rẹ̀, ati ohun èlo mimọ́ Ọlọrun, sinu ile na ti a o kọ́ fun orukọ Oluwa.
Pín
Kà I. Kro 22I. Kro 22:19 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí náà, ẹ fi tọkàntọkàn wá OLUWA Ọlọrun yín nisinsinyii. Ẹ múra kí ẹ kọ́ ilé ìsìn fún OLUWA Ọlọrun, kí ẹ baà lè gbé Àpótí Majẹmu OLUWA ati gbogbo ohun èlò mímọ́ fún ìsìn Ọlọrun lọ sinu ilé tí ẹ óo kọ́ fún OLUWA.”
Pín
Kà I. Kro 22I. Kro 22:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Nísinsin yìí, ẹ ṣí ọkàn yin páyà àti àyà yín sí àti wá OLúWA Ọlọ́run yín. Bẹ́ẹ̀ sì ni kọ́ ibi mímọ́ fún OLúWA Ọlọ́run. Bẹ́ẹ̀ ni kí ìwọ kí ó le gbé àpótí ẹ̀rí ti májẹ̀mú OLúWA àti ohun èlò mímọ́ tí ó jẹ́ ti Ọlọ́run, sínú ilé OLúWA tí a o kọ́ fún orúkọ OLúWA.”
Pín
Kà I. Kro 22