Nigbana ni awọn igi igbo yio ma ho niwaju Oluwa, nitori ti o mbọ wá ṣe idajọ aiye.
Àwọn igi igbó yóo kọrin ayọ̀ níwájú OLUWA, nítorí ó wá láti ṣe ìdájọ́ ayé.
Nígbà náà ni igi igbó yóò kọrin, Wọn yóò kọrin fún ayọ̀ níwájú OLúWA, nítorí tí ó wá láti ṣèdájọ́ ayé.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò