I. Kro 16:24
I. Kro 16:24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ sọ̀rọ ogo rẹ̀ ninu awọn keferi; ati iṣẹ-iyanu rẹ̀ ninu gbogbo enia.
Pín
Kà I. Kro 16I. Kro 16:24 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ kéde ògo rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ polongo iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan!
Pín
Kà I. Kro 16