Sekariah 10:6

Sekariah 10:6 YCB

“Èmi o sì mú ilé Juda ní agbára, èmi o sì gba ilé Josẹfu là, èmi ó sì tún mú wọn padà nítorí mo tí ṣàánú fún wọn, ó sì dàbí ẹni pé èmi kò ì tì í ta wọ́n nù; nítorí èmi ni OLúWA Ọlọ́run wọn, èmi o sì gbọ́ tiwọn