Ìbùkún ni fún àwọn ènìyàn tí wọn mọ ohùn ayọ̀ nì, OLúWA wọ́n ó máa rìn ní ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ. Wọn ń ṣògo nínú orúkọ rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́, wọn ń yin òdodo rẹ. Nítorí ìwọ ni ògo agbára wọn; nípa ojúrere ni ìwo wá ń ṣògo. Nítorí ti OLúWA ni asà wa, ọba wa sì ni Ẹni Mímọ́ Israẹli.
Kà Saamu 89
Feti si Saamu 89
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 89:15-18
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò