Saamu 6:2-3

Saamu 6:2-3 YCB

Ṣàánú fún mi, OLúWA, nítorí èmi ń kú lọ; OLúWA, wò mí sán, nítorí egungun mi wà nínú ìnira. Ọkàn mi wà nínú ìrora. Yóò ti pẹ́ tó, OLúWA, yóò ti pẹ́ tó?