ORIN DAFIDI 6:2-3

ORIN DAFIDI 6:2-3 YCE

Ṣàánú mi, OLUWA, nítorí àárẹ̀ mú ọkàn mi, OLUWA, wò mí sàn nítorí ara ń ni mí dé egungun. Ọkàn mi kò balẹ̀ rárá, yóo ti pẹ́ tó, OLUWA, yóo ti pẹ́ tó?