Saamu 39:7-8

Saamu 39:7-8 YCB

“Ṣùgbọ́n ní ìsinsin yìí, OLúWA, kín ni mo ń dúró dè? Ìrètí mí ń bẹ ní ọ̀dọ̀ rẹ. Gbà mí lọ́wọ́ ìrékọjá mi gbogbo. Kí o má sì sọ mí di ẹni ẹ̀gàn àwọn ènìyàn búburú.