Saamu 27:9-10

Saamu 27:9-10 YCB

Má ṣe fi ojú rẹ pamọ́ kúrò lọ́dọ̀ mi, má ṣe fi ìbínú sá ìránṣẹ́ rẹ tì; ìwọ tí o ti jẹ́ olùrànlọ́wọ́ mi, Má ṣe fi mí sílẹ̀, má sì ṣe kọ̀ mí, háà! Ọlọ́run ìgbàlà mi. Bí ìyá àti baba bá kọ̀ mí sílẹ̀, OLúWA yóò tẹ́wọ́ gbà mí.