OLúWA, ìwọ ni mo gbé ọkàn mi sókè sí. Ọlọ́run, èmi gbẹ́kẹ̀lé ọ; Má ṣe jẹ́ kí ojú ó tì mí Má ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi ó yọ̀ mí. Ẹni tí ó dúró tì ọ́ ojú kì yóò tì í, àwọn tí ń ṣẹ̀ láìnídìí ni kí ojú kí ó tì. Fi ọ̀nà rẹ hàn mí, OLúWA, kọ mi ní ipa tìrẹ; ṣe amọ̀nà mi nínú òtítọ́ ọ̀ rẹ, kí o sì kọ́ mi, Nítorí ìwọ ni Ọlọ́run ìgbàlà mi; ìwọ ni mo dúró tì ní gbogbo ọjọ́.
Kà Saamu 25
Feti si Saamu 25
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 25:1-5
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò