Saamu 18:6

Saamu 18:6 YCB

Nínú ìpọ́njú mo ké pe OLúWA; Mo sọkún sí OLúWA mi fún ìrànlọ́wọ́. Láti inú tẹmpili rẹ̀, ó gbọ́ igbe mi; ẹkún mi wá sí iwájú rẹ̀, sí inú etí rẹ̀.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 18:6