Ẹ fi ìyìn fún OLúWA. Ẹ fi ìyìn fún Ọlọ́run ní ibi mímọ́ rẹ̀ Ẹ yìn ín nínú agbára ọ̀run rẹ̀. Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ agbára rẹ̀. Ẹ yìn ín fún títóbi rẹ̀ tí ó tayọ̀. Ẹ fi ohùn ìpè yìn ín. Ẹ fi ohun èlò orin yìn ín. Ẹ fi ohun èlò orin àti ijó yìn ín fi ohun èlò orin olókùn àti ìpè yìn ín Ẹ yìn ín pẹ̀lú aro olóhùn òkè, Ẹ yìn ín lára aro olóhùn gooro.
Kà Saamu 150
Feti si Saamu 150
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 150:1-5
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò