Saamu 136:1-3

Saamu 136:1-3 YCB

Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA nítorí tí ó ṣeun; nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run àwọn ọlọ́run: nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa àwọn olúwa, nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 136:1-3