Nígbà tí OLúWA mú ìkólọ Sioni padà, àwa dàbí ẹni tí ó ń lá àlá. Nígbà náà ni ẹnu wa kún fún ẹ̀rín, àti ahọ́n wa kọ orin; nígbà náà ni wọ́n wí nínú àwọn kèfèrí pé, OLúWA ṣe ohun ńlá fún wọn. OLúWA ṣe ohun ńlá fún wa; nítorí náà àwa ń yọ̀.
Kà Saamu 126
Feti si Saamu 126
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 126:1-3
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò