Nígbà náà wọ́n ń kígbe sókè sí OLúWA nínú ìdààmú wọn, ó sì mú wọn jáde nínú ìṣòro wọn. Ó sọ ìjì di ìdákẹ́rọ́rọ́ bẹ́ẹ̀ ni ríru omi rẹ̀ dúró jẹ́ẹ́; Inú wọn dùn nígbà tí ara wọn balẹ̀, ó mú wọn lọ sí ibi tí ọkàn wọn lọ
Kà Saamu 107
Feti si Saamu 107
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 107:28-30
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò