Òwe 5:21-23

Òwe 5:21-23 YCB

Nítorí ọ̀nà ènìyàn kò fi ara sin rárá fún OLúWA Ó sì ń gbé gbogbo ọ̀nà rẹ̀ yẹ̀ wò Ìwà búburú ènìyàn búburú ni yóò mú kó bọ́ sínú okùn; okùn ẹ̀ṣẹ̀ ara rẹ̀ yóò sì dìímú. Yóò kú ní àìgba ẹ̀kọ́ ìwà òmùgọ̀ ara rẹ̀ yóò sì mú kí ó máa ṣìnà kiri.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Òwe 5:21-23

Òwe 5:21-23 - Nítorí ọ̀nà ènìyàn kò fi ara sin rárá fún OLúWA
Ó sì ń gbé gbogbo ọ̀nà rẹ̀ yẹ̀ wò
Ìwà búburú ènìyàn búburú ni yóò mú kó bọ́ sínú okùn;
okùn ẹ̀ṣẹ̀ ara rẹ̀ yóò sì dìímú.
Yóò kú ní àìgba ẹ̀kọ́
ìwà òmùgọ̀ ara rẹ̀ yóò sì mú kí ó máa ṣìnà kiri.