Òwe 17:14-15

Òwe 17:14-15 YCB

Bíbẹ̀rẹ̀ ìjà dàbí ẹni tí ó dá ojú fún adágún omi nítorí náà mẹ́nu kúrò nínú ọ̀rọ̀ kí ó tó di ìjà. Gbígbé ẹ̀bi fún aláre àti dídá ẹni jàre lẹ́bi, OLúWA kórìíra méjèèjì.