ÌWÉ ÒWE 17:14-15

ÌWÉ ÒWE 17:14-15 YCE

Ìbẹ̀rẹ̀ ìjà dàbí kí eniyan ya odò tí wọn sé, dá a dúró kí ó tó di ńlá. Ẹni tí ń gbé àre fún ẹlẹ́bi ati ẹni tí ń gbé ẹ̀bi fún aláre, OLUWA kórìíra ekinni-keji wọn.