Òwe 16:6-7
Òwe 16:6-7 BMYO
Nípasẹ̀ ìfẹ́ àti òtítọ́ a ṣe ètùtù ẹ̀ṣẹ̀ nípasẹ̀ ìbẹ̀rù OLúWA ènìyàn sá fún ibi. Nígbà tí ọ̀nà ènìyàn bá tẹ́ OLúWA lọ́rùn, yóò mú kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ gàn án bá a gbé ní àlàáfíà.