Òwe 16:1-2

Òwe 16:1-2 YCB

Ti ènìyàn ni ìgbèrò inú ọkàn ṣùgbọ́n láti ọ̀dọ̀ OLúWA ni ìdáhùn ahọ́n ti ń wá. Gbogbo ọ̀nà ènìyàn ni ó dàbí i pé ó dára lójú ara rẹ̀ ṣùgbọ́n OLúWA ló ń díwọ̀n èrò inú ọkàn.