Òwe 14:11-12

Òwe 14:11-12 YCB

A ó pa ilé ènìyàn búburú run Ṣùgbọ́n àgọ́ olódodo yóò máa gbèrú sí i. Ọ̀nà kan wà tí ó dàbí i pé ó dára lójú ènìyàn, ṣùgbọ́n ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín, a máa jásí ikú.