ÌWÉ ÒWE 14:11-12

ÌWÉ ÒWE 14:11-12 YCE

Ìdílé ẹni ibi yóo parun, ṣugbọn ilé olódodo yóo máa gbèrú títí lae. Ọ̀nà kan wà tí ó dàbí ẹni pé ó tọ́ lójú eniyan, ṣugbọn òpin rẹ̀, ikú ni.