Òwe 12:2-3

Òwe 12:2-3 YCB

Ènìyàn rere gba ojúrere lọ́dọ̀ OLúWA ṣùgbọ́n ènìyàn ètè búburú ni yóò dá lẹ́bi. A kò lè fi ẹsẹ̀ ènìyàn múlẹ̀ nípa ìwà búburú ṣùgbọ́n a kò le è fa olódodo tu.