Òwe 10:20-21

Òwe 10:20-21 YCB

Ètè olódodo jẹ́ ààyò fàdákà ṣùgbọ́n ọkàn ènìyàn búburú kò níye lórí. Ètè olódodo ń bọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ṣùgbọ́n aláìgbọ́n ń kú nítorí àìlóye.