Numeri 30:1-2

Numeri 30:1-2 YCB

Mose sì sọ fún olórí àwọn ẹ̀yà ọmọ Israẹli pé: “Èyí ni ohun tí OLúWA pàṣẹ: Nígbà tí ọkùnrin kan bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ sí OLúWA tàbí búra láti fi de ara rẹ̀ ní ìdè kí òun má bà ba ọ̀rọ̀ rẹ̀ jẹ́ kí ó ṣe gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe sọ.