Jeremiah 30:17

Jeremiah 30:17 YCB

Ṣùgbọ́n èmi yóò fi ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìlera fún yín, èmi yóò sì wo ọ̀gbẹ́ yín sàn,’ ni OLúWA wí, ‘nítorí tí a pè yín ní alárìnkiri Sioni tí gbogbo ènìyàn dágunlá sí.’