Isaiah 42:12-13

Isaiah 42:12-13 YCB

Jẹ́ kí wọn fi ògo fún OLúWA àti kí wọn sì kéde ìyìn rẹ̀ ní erékùṣù. OLúWA yóò rìn jáde gẹ́gẹ́ bí i ọkùnrin alágbára, yóò ru owú sókè bí ológun; yóò kígbe nítòótọ́, òun yóò ké igbe ogun, òun yóò sì ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá rẹ̀.