Heberu 1:11-12

Heberu 1:11-12 YCB

Wọn yóò ṣègbé, ṣùgbọ́n ìwọ yóò wà síbẹ̀ gbogbo wọn ni yóò di àkísà bí ẹ̀wù. Ní kíká ni ìwọ yóò ká wọn bí aṣọ, bí ìpààrọ̀ aṣọ ni a ó sì pààrọ̀ wọn. Ṣùgbọ́n ìwọ fúnrarẹ̀ kì yóò yípadà àti pé ọdún rẹ kì yóò ní òpin.”