Gẹnẹsisi 28:13

Gẹnẹsisi 28:13 YCB

OLúWA sì dúró lókè rẹ̀, ó sì wí pé, “Èmi ni OLúWA, Ọlọ́run baba rẹ Abrahamu àti Ọlọ́run Isaaki, ìwọ àti ìran rẹ ni èmi yóò fi ilẹ̀ tí ìwọ dùbúlẹ̀ sórí rẹ̀ yìí fún.