Eksodu 16:8

Eksodu 16:8 YCB

Mose tún wí pé, “Ẹ̀yin yóò mọ pé OLúWA ni, nígbà ti ó bá fún un yín ni ẹran ni ìrọ̀lẹ́ àti gbogbo oúnjẹ ti ẹ̀yin ń fẹ́ ni òwúrọ̀, nítorí kíkùn ti ẹ̀yin ń kùn sí i. Ta ni àwa? Ẹ̀yin kò kùn sí àwa, OLúWA ni ẹ̀yin kùn sí i.”