Deuteronomi 10:8

Deuteronomi 10:8 YCB

Ní ìgbà yìí ni OLúWA yan àwọn ẹ̀yà Lefi láti máa ru àpótí ẹ̀rí OLúWA, láti máa dúró níwájú OLúWA láti ṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́, àti láti fi orúkọ OLúWA súre bí wọ́n ti ń ṣe títí di òní yìí.