Daniẹli Ìfáàrà
Ìfáàrà
Ohun tí ó ṣe pàtàkì tí ìwé yìí sọ̀rọ̀ lé lórí ni títóbi agbára Ọlọ́run, “Ọlọ́run tí ó ga jù ní agbára lórí Ìjọba ènìyàn” (5.21). Àwọn ìran Daniẹli máa ń fi Ọlọ́run hàn bí aṣẹ́gun. Títóbi agbára rẹ̀ ni ó ṣàlàyé nínú ìṣípayá “Ìjọba ayé ti di ìjọba Olúwa wa àti tí Kristi yóò sì jẹ ọba láé àti láéláé.”
Ìwé yìí jẹ́ ìtàn ohun tó ṣẹlẹ̀, àti ìṣípayá. Ó kọ ọ́ fún ìgbà tí ènìyàn bá wà nínú ìnira, ó sì tún jẹ́ ìwé tó mú àwọn ènìyàn Ọlọ́run lọ́kàn lé, tó sì mú ìgbàgbọ́ ènìyàn dúró.
Kókó-ọ̀rọ̀
i. Daniẹli àti àwọn ọ̀rẹ́ ẹ̀ rẹ̀ lọ sí ìgbèkùn 1.1–6.28.
ii. Ìran tí Daniẹli rí nípa ẹranko 7.1-28.
iii. Ìran tí Daniẹli rí nípa àgbò àti ewúrẹ́ 8.1–9.27.
iv. Ìránṣẹ́ òde ọ̀run 10.1–11.45.
v. Àkókò ìkẹyìn 12.1-13.
Àwon tá yàn lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí:
Daniẹli Ìfáàrà: YCB
Ìsàmì-sí
Pín
Daako
Ṣé o fẹ́ fi àwọn ohun pàtàkì pamọ́ sórí gbogbo àwọn ẹ̀rọ rẹ? Wọlé pẹ̀lú àkántì tuntun tàbí wọlé pẹ̀lú àkántì tí tẹ́lẹ̀
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc.
A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé.
Yoruba Contemporary Bible
Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.®
Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.