Amosi 5:23-24

Amosi 5:23-24 YCB

Ẹ gbé ariwo orin yín sẹ́yìn Èmi kò ní fetísí ohun èlò orin yín. Jẹ́ kí òtítọ́ sàn bí odò àti òdodo bí ìsun tí kò lé è gbẹ!