2 Samuẹli 10:12

2 Samuẹli 10:12 YCB

Mú ọkàn lè, jẹ́ kí a ṣe onígboyà nítorí àwọn ènìyàn wa, àti nítorí àwọn ìlú Ọlọ́run wa; OLúWA yóò sì ṣe èyí tí ó dára lójú rẹ̀.”