2 Kọrinti 3:12

2 Kọrinti 3:12 YCB

Ǹjẹ́ nítorí náà bí a tí ní irú ìrètí bí èyí, àwa ń fi ìgboyà púpọ̀ sọ̀rọ̀.