2 Kronika 20:19

2 Kronika 20:19 YCB

Nígbà náà díẹ̀ lára àwọn ọmọ Lefi àti àwọn ọmọ Kohati àti àwọn ọmọ Kora sì dìde dúró wọ́n sì sin OLúWA, Ọlọ́run Israẹli, pẹ̀lú ohùn ariwo ńlá.