1 Kọrinti 12:19

1 Kọrinti 12:19 YCB

Bí gbogbo wọn bá sì jẹ́ ọ̀kan ṣoṣo nínú ẹ̀yà ara, níbo ni ara yóò gbé wà.