Rom 8:5-8

Rom 8:5-8 YBCV

Nitori awọn ti o wà nipa ti ara, nwọn a mã ro ohun ti ara; ṣugbọn awọn ti o wà nipa ti Ẹmí, nwọn a mã ro ohun ti Ẹmí. Nitori ero ti ara ikú ni; ṣugbọn ero ti Ẹmí ni iye ati alafia: Nitori ero ti ara ọtá ni si Ọlọrun: nitori ki itẹriba fun ofin Ọlọrun, on kò tilẹ le ṣe e. Bẹ̃li awọn ti o wà ninu ti ara, kò le wù Ọlọrun.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Rom 8:5-8

Rom 8:5-8 - Nitori awọn ti o wà nipa ti ara, nwọn a mã ro ohun ti ara; ṣugbọn awọn ti o wà nipa ti Ẹmí, nwọn a mã ro ohun ti Ẹmí.
Nitori ero ti ara ikú ni; ṣugbọn ero ti Ẹmí ni iye ati alafia:
Nitori ero ti ara ọtá ni si Ọlọrun: nitori ki itẹriba fun ofin Ọlọrun, on kò tilẹ le ṣe e.
Bẹ̃li awọn ti o wà ninu ti ara, kò le wù Ọlọrun.Rom 8:5-8 - Nitori awọn ti o wà nipa ti ara, nwọn a mã ro ohun ti ara; ṣugbọn awọn ti o wà nipa ti Ẹmí, nwọn a mã ro ohun ti Ẹmí.

Bẹ̃li awọn ti o wà ninu ti ara, kò le wù Ọlọrun.