O. Daf 28:8-9

O. Daf 28:8-9 YBCV

Oluwa li agbara wọn, on si li agbara igbala ẹni-ororo rẹ̀. Gbà awọn enia rẹ là, ki o si busi ilẹ-ini rẹ: ma bọ́ wọn pẹlu, ki o si ma gbé wọn leke lailai.