O. Daf 134

134
Ẹ yin OLUWA
1Ẹ kiyesi i, ẹ fi ibukún fun Oluwa, gbogbo ẹnyin iranṣẹ Oluwa, ti nduro ni ile Oluwa li oru.
2Ẹ gbé ọwọ nyin soke si ibi-mimọ́, ki ẹ si fi ibukún fun Oluwa.
3Oluwa ti o da ọrun on aiye, ki o busi i fun ọ lati Sioni wá.

Àwon tá yàn lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí:

O. Daf 134: YBCV

Ìsàmì-sí

Pín

Daako

None

Ṣé o fẹ́ fi àwọn ohun pàtàkì pamọ́ sórí gbogbo àwọn ẹ̀rọ rẹ? Wọlé pẹ̀lú àkántì tuntun tàbí wọlé pẹ̀lú àkántì tí tẹ́lẹ̀