Owe 21:14-16

Owe 21:14-16 YBCV

Ọrẹ ikọkọ, o tù ibinu: ati ẹ̀bun ni iṣẹpo-aṣọ, o tù ibinu lile. Ayọ̀ ni fun olododo lati ṣe idajọ: ṣugbọn iparun ni fun awọn oniṣẹ ẹ̀ṣẹ. Ẹniti o ba yà kuro li ọ̀na oye, yio ma gbe inu ijọ awọn okú.