Owe 12:5-7

Owe 12:5-7 YBCV

Ìro olododo tọ́: ṣugbọn ìgbimọ awọn enia buburu, ẹ̀tan ni. Ọ̀rọ enia buburu ni lati luba fun ẹ̀jẹ: ṣugbọn ẹnu aduro-ṣinsin ni yio gbà wọn silẹ. A bì enia buburu ṣubu, nwọn kò si si: ṣugbọn ile olododo ni yio duro.