Filp 1:3-6

Filp 1:3-6 YBCV

Mo dupẹ lọwọ Ọlọrun mi fun gbogbo iranti nyin ti mo nṣe, Nigbagbogbo ninu gbogbo adura mi fun nyin li emi nfi ayọ̀ bẹ̀bẹ, Nitori ìdapọ nyin ninu ihinrere lati ọjọ kini wá titi fi di isisiyi. Ohun kan yi sa da mi loju, pe ẹniti o ti bẹ̀rẹ iṣẹ rere ninu nyin, yio ṣe aṣepe rẹ̀ titi fi di ọjọ Jesu Kristi

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Filp 1:3-6

Filp 1:3-6 - Mo dupẹ lọwọ Ọlọrun mi fun gbogbo iranti nyin ti mo nṣe,
Nigbagbogbo ninu gbogbo adura mi fun nyin li emi nfi ayọ̀ bẹ̀bẹ,
Nitori ìdapọ nyin ninu ihinrere lati ọjọ kini wá titi fi di isisiyi.
Ohun kan yi sa da mi loju, pe ẹniti o ti bẹ̀rẹ iṣẹ rere ninu nyin, yio ṣe aṣepe rẹ̀ titi fi di ọjọ Jesu KristiFilp 1:3-6 - Mo dupẹ lọwọ Ọlọrun mi fun gbogbo iranti nyin ti mo nṣe,
Nigbagbogbo ninu gbogbo adura mi fun nyin li emi nfi ayọ̀ bẹ̀bẹ,
Nitori ìdapọ nyin ninu ihinrere lati ọjọ kini wá titi fi di isisiyi.
Ohun kan yi sa da mi loju, pe ẹniti o ti bẹ̀rẹ iṣẹ rere ninu nyin, yio ṣe aṣepe rẹ̀ titi fi di ọjọ Jesu Kristi

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Filp 1:3-6