Mat 20:33-34
Mat 20:33-34 YBCV
Nwọn wi fun u pe, Oluwa, ki oju wa ki o le là. Bẹ̃ni Jesu ṣãnu fun wọn, o si fi ọwọ́ tọ́ wọn li oju: lọgan oju wọn si là, nwọn si tọ̀ ọ lẹhin.